Biochemistry

Biochemistry, nígbàmíràn wọ́n máa ń pèé ní biological chemistry, jẹ́ ìmọ̀  ìlànà kẹ́míkà àgọ́ ara àtí ìbáṣepọ̀ wọn pẹ̀lú ohun ẹlẹmí.[1] Nípa ṣíṣe àkóso lílọ-bíbọ̀  iṣẹ́ lágọ́ ara nípasẹ̀ ìtalólobo ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà àti lílọ-bíbọ̀ agbára kẹ́míkà làtàrí gbogbo ìbáṣepọ̀ kẹ́míka nínú ara, ìlànà kẹ́míkà nínú ara yìí ní ó máa ń ṣe ìmúgbòòrò bí ara ṣe ń ṣiṣẹ́. Ní bíi ogún ọrundún sẹ́yìn, biochemistry ti ṣe àṣeyọrí lórí bí a ṣe lè ṣàlàyé lórí ìlànà ìgbéayé tí ó ni ṣe pẹ̀lú ìmọ ohun ẹlẹ́mí làti ìmọ̀ ewéko sí ìmọ̀ ìlera, sí ìmọ̀ ìṣiṣẹ́àbínimọ́ ní wọ́n ní ṣe pẹ̀lú ìwádí ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà lágọ́ ara.[2] Loní, ìdojúkọ ìwádí ní biochemistry dá lórí òye bí biological molecules ṣe ń f ìlànà tó ń ṣẹlẹ̀ nínú àwọn ètò ẹ̀yà ara.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. "Biochemistry". acs.org. 
  2. Voet (2005), p. 3.
  3. Karp (2009), p. 2.

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.