Edwin Hubble
| Edwin Powell Hubble | |
|---|---|
| Ìbí | Oṣù Kọkànlá 20, 1889 Marshfield, Missouri, U.S. |
| Aláìsí | September 28, 1953 (ọmọ ọdún 63) San Marino, California |
| Ibùgbé | United States |
| Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
| Pápá | Astronomy |
| Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Chicago Mount Wilson Observatory |
| Ibi ẹ̀kọ́ | University of Chicago University of Oxford |
| Ó gbajúmọ̀ fún | Big Bang Hubble's law Redshift Hubble sequence |
| Influenced | Allan Sandage |
| Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Bruce Medal 1938 |
Edwin Powell Hubble (November 20, 1889 – September 28, 1953) je atorawo ara Amerika to se alaye bi agbalaaye se ri nipa sisafihan pe awon galaksi miran na wa leyin Galaksi Milky Way wa. Bakanna o tun sawari pe iyi "isele Doppler" (ni pato "redshift") to je kikiyesi ninu light spectra lati awon galaksi miran unposi ni iye si bi galaksi pato kan se jinnasi lati Aye. Ibasepo yi lo unje ofin Hubble, o si fihan pe agbalaaye unfesi.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.