Iko

Ikọ́ jẹ́ ohun tí ó máa ń wáyé láti mú ikun àti ìdọ́tí bíi eruku tàbí èéfín kúrò ní àyà wa. Ikọ́ fún ra rẹ̀ kìí se àìsàn ṣùgbọ́n wíwú Ikọ́ léraléra lè jẹ́ àmì wípé àìsàn wà lára. Ikọ́ jẹ́ ọ̀kan lára nkan tí ènìyàn ó ní agbára lé lórí, kódà bí ènìyàn kò bá fẹ́ wúkọ́, bí ìdọ́tí tàbí àìtó bá ti wọ ọ̀nà ofun tàbí ẹ̀dọ̀fóró, ikó ma wáyé láti tíì síta, ènìyàn o le dá ikó dúró làílàí[1]
Ikọ́ wà lára àwọn ọ̀nà tí ara ń fi dàbọ̀ bo ara rẹ̀. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ikọ́ jẹ́ nkan tí ènìyàn kò lágbára lórí, ènìyàn fún ra rẹ̀ le wúkọ́ láti mú ìkan kúrò ní ọ̀nà ọ̀fun fúnra rẹ̀. Ọ̀pọ̀lopọ̀ àrùn tí ó ń fa ikọ́ ni ó máa ń lọ fúnra rẹ̀ ní àárín ọ̀ṣẹ̀ mẹ́ta tí wọn kò sì nílò ìtójú.[2][3]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ Association, American Lung (2022-11-21). "Learn About Cough". American Lung Association. Retrieved 2023-02-09.
- ↑ pennmedicine.org https://www.pennmedicine.org/for-patients-and-visitors/patient-information/conditions-treated-a-to-z/cough. Retrieved 2023-02-09. Missing or empty
|title=(help) - ↑ "Symptoms and causes". Mayo Clinic. 2019-07-09. Retrieved 2023-02-09.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.