Shadow Parties
Shadow Parties jẹ́ fíìmù eré òṣèlú Nàìjíríà kan ti ọdún 2021 tí Yemi Amodu jẹ́ oludari ati olùgbéjáde. Àwọn òṣèré fíìmù náà niYemi Blaq, Omotola Jalade-Ekeinde, Toyin Abraham, Jide Kosoko, Sola Sobowale, Magdalena Korpas, àti Lucien Morgan. wọn ṣe àfihàn rẹ̀ lori Netflix ni ọjọ kẹfà Oṣu Kẹsan ọdún 2021. [1]
Ìdálélórí
Àkòrí fíìmù náà dá lóri ìjà aráàlú tó wáyé nínú èyí tí Aremu tó wá láti Aje, ìlú kan tó wà laduugbo Iludun, níbi tí wọn ti bí ìyàwó rẹ̀, Arike, ti gbogbo ènìyàn mọ̀ fún ogun àwọn ọmọ ẹgbẹ́, èyí ti o ti mú ẹ̀mí àwọn òbí Arike lọ́wọ́. Àwọn ará ìlú méjèjì yi bọ́ sínú ogun lẹ́yìn tí àwọn ẹbí Aremu pinnu láti sun ìyàwó àti ọmọ rẹ̀ laáyè wí pé ọ̀tá ni, eléyìí ló mú ki àwọn Iludun bẹrẹ ìjà tí Lowo sì ṣáájú wọn, ẹgbọn Arike.
Àwọn òṣèré
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.