Still Falling

Still Falling
Fáìlì:Still Falling Poster.jpg
AdaríKarachi Atiya
Dimbo Atiya
Àwọn òṣèréDaniel Etim Effiong
Sharon Ooja
Kunle Remi
Déètì àgbéjáde
  • 12 Oṣù Kejì 2021 (2021-02-12)
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish
Owó àrígbàwọlé₦27.7 million[1]

Still Falling jẹ́ eré ìfẹ́ tí wọ́n ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún un 2021 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Karachi Atiya and Dimbo Atiya ni wọ́n jẹ́ olùdarí eré yìí . Àwọn òṣèré tí wọ́n kópa nínú fíìmù yìí gẹ́gẹ́ bíi olú akópa ni Daniel Etim Effiong, Sharon Ooja, Kunle Remi.[2] Wọ́n ṣe àfihàn eré yìí ní tíátà ní ọjọ́ Kejìlá, oṣù kejì ọdún un 2021, ní alẹ́ ẹ àìsùn àyájọ́ ọjọ́ olólùfẹ́ Valentine's Eve. Abuja ni ìbùdó ìtàn eré yìí.[3]


Àwọn Òṣèrẹ́ Akópa

  • Sharon Ooja kópa gẹ́gẹ́ bíi Bono
  • Daniel Etim Effiong kópa gẹ́gẹ́ bíi Lagi
  • Bethel Njoku kópa gẹ́gẹ́ bíi Eric
  • Laura Fidel kópa gẹ́gẹ́ bíi Intoh
  • Eddy Madaki kópa gẹ́gẹ́ bíi Truemoney Executive
  • Lulu Okonkwo kópa gẹ́gẹ́ bíi Kore
  • Panam Percy Paul kópa gẹ́gẹ́ bíi Bishop Gowon
  • Chavala Yaduma kópa gẹ́gẹ́ bíi Xo
  • Liz Ameye kópa gẹ́gẹ́ bíi Ìya Bono / Abilékọ Kuku
  • Kunle Remi kópa gẹ́gẹ́ bíi Tunde
  • Abundance Effiong kópa gẹ́gẹ́ bíi Associate Pastor
  • Frank Abumere kópa gẹ́gẹ́ bíi Ọ̀gá Ọlọ́pàá
  • Clara Chapp-Jumbo kópa gẹ́gẹ́ bíi Bono's Assistant
  • Innocent Enefola kópa gẹ́gẹ́ bíi Bartender
  • Lebechi Olorunfemi Miwa kópa gẹ́gẹ́ bíi Air Hostess
  • Bally O. Nosike kópa gẹ́gẹ́ bíi Ọlọ́pàá
  • Ann Ogiehor kópa gẹ́gẹ́ bíi Asọ̀ròyìn
  • Adetoro Okide kópa gẹ́gẹ́ bíi Adarí ní Pápákọ̀-Òfurufú


Alámòójútó eré

  • Dimbo Atiya - Karachi Atiya ni wọ́n darí eré yìí
  • Dimbo Atiya ló kọ eré yii
  • Prince Aboki ni ó ṣe àgbéjáde eré yìí
  • Tom Robson ni ayàwòrán eré yii
  • Johnson Awolola ni alátùn-ún-ṣe eré yìí
  • Mnena Akpera ló ṣàfihàn àwọn ẹ̀dá ìtàn
  • Shaddi Justin ló ṣe àtúnṣe orin nínú eré yìí

Àwọn Ìtọ́kasí


Àdàkọ:Nigeria-film-stub Àdàkọ:2020s-romantic-drama-film-stub

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.