The Narrow Path
| The Narrow Path | |
|---|---|
| [[File:Fáìlì:Movie poster for The Narrow Path.jpg|200px|alt=]] | |
| Adarí | Túndé Kèlání |
| Òǹkọ̀wé | Túndé Kèlání Niji Akanni |
| Àwọn òṣèré | Sola Asedeko Ayo Badmus Khabirat Kafidipe |
| Orin | Beautiful Nubia Seun Owoaje |
| Ìyàwòrán sinimá | Lukaan Abdulrahman Tunde Kelani |
| Olóòtú | Mumin Wale Kelani Frank Efe Patrick |
| Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Mainframe Film and Television Productions |
| Olùpín | Mainframe Film and Television Productions |
| Déètì àgbéjáde | 2006 |
| Àkókò | 95 minutes |
| Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
| Èdè | English and Yoruba |
The Narrow Path Ni eré oníṣẹ́ tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2006, tí alàgbà Túndé Kèlání gbé jáde tí ó sì darí rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Wọ́n ṣe àfàyọ eré yí láti inú ìwé onítàn The Virgin, ìwé tí Bayo Adebowale ke jáde.[2][3][4]
Agbékalẹ̀ eré náà
Eré yí ni ó sọ nípa ìṣòro tí ẹ̀dá ìtàn kan tí ó jẹ́ Awẹ̀ró tí ó ní láti mú ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin méjì Ọdẹ́jìmí ati Lápàdé tí ó jẹ́ ọmọ ọdẹ tí wọ́n ń dẹnu ifẹ́ kọ. [5][6][7]
Àwọn Ẹ̀dá-ìtàn
- Sola Asedeko as Awero
- Segun Adefila as Dauda
- Ayo Badmus as Lapade
- Seyi Fasuyi as Odejimi
- Khabirat Kafidipe
- Joke Muyiwa
- Olu Okekanye
- Eniola Olaniyan
Àwọn itọ́ka sí
- ↑ Ekenyerengozi, Michael Chima (2013). NOLLYWOOD MIRROR®. ISBN 9781304729538. https://books.google.com/books?id=RL01BgAAQBAJ&q=The+Narrow+Path-Tunde+Kelani+film&pg=PA21.
- ↑ "Continual Re-enchantment: Tunde Kelani's Village Films and the Spectres of Early African Cinema". framescinemajournal.com. Archived from the original on 2020-11-01. Retrieved 2021-05-20.
- ↑ "Narrow Path by Tunde Kelani". naijarules.com. Archived from the original on 2015-04-09. Retrieved 2021-05-20.
- ↑ Kerr, David; Banham, Martin; Gibbs, James; Plastow, Jane; Osofisan, Femi (2011). Media and Performance. ISBN 9781847010384. https://books.google.com/books?id=dFzMC-nHqi4C&q=The+Narrow+Path-Tunde+Kelani+film&pg=PA38.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2015-06-29. Retrieved 2021-05-20.
- ↑ "The Narrow Path". African Film Festival Inc.
- ↑ http://allafrica.com/stories/200802110080.html
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.