Addis Ababa
Addis Ababa jẹ́ olú-ìlú Ethiopia, ó sì tún jẹ́ ìpínlẹ̀ àgbègbè Oromia Pẹ̀lú ìṣirò olùgbé tó tó 2,739,551 gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn Odún 2007, ó jẹ́ ìlú tó tóbi jù lọ ní orílẹ̀-èdè náà àti èyí kejìlá tó tóbi jù lọ ní Áfríkà. Ní gíga 2,355 mítà (7,726 ẹsẹ̀ bàtà), ó jẹ́ olú-ìlú kẹrin tó ga jù lọ ní ayé àti èyí tó ga jù lọ ní Áfríkà.
Click to read more »