77 Bullets
| 77 Bullets | |
|---|---|
| Adarí | Adebayo Tijani |
| Olùgbékalẹ̀ | Mercy Aigbe |
| Àwọn òṣèré | Temitope Solaja, Ibrahim Yekini and Eniola Ajao |
| Déètì àgbéjáde | 2019 |
| Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
| Èdè | Yoruba |
77 Bullet jẹ́ fíimù ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2019, tí Mercy Aigbe gbé jáde, tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ Adebayo Tijani.[1][2][3][4]
Ó jẹ́ fíìmù ajẹ́mọ́-ìṣẹ̀lè-tó -le, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ gbajúmọ̀ òṣèré bí iTemitope Solaja, Ibrahim Yekini àti Eniola Ajao kópa nínú rẹ̀.[5] [6]
Ìsọníṣókí
Fíìmù náà sọ ìtàn ọlọ́ṣà kan tí kò láàánú, tó sì ní ìhámọ́ra oògun tó fi ń ba àwọn aráàlú lẹ́rù, tó sì ń ṣẹ̀rù bà wọ́n. Nígbẹ̀yìn gbẹ́yín, ọwọ́ tẹ̀ ẹ́. Fíìmù náà lọ́ bákan bákan nígbà tí ọ̀dáràn yìí fojú kan ilé-ẹjọ́ tí ìkejì rẹ̀ sì jẹ́ adájọ ní ilé-ẹjọ́ náà.[7][8]
Ìṣàfihàn
Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ fíìmù yìí wáyé lórí YouTube ní 20 December, ọdún 2019.
Àwọn akópa
- Mercy Aigbe
- Temitope Solaja
- Ibrahim Yekini
- Eniola Ajao
- Titi Osinowo
- Bimbo Afolayan
- Eniola Afeez
- Taiwo Ibikunle
- Adeniyi Johnson
- Yinka Quadri
- ↑ Bada, Gbenga (2019-12-19). "Mercy Aigbe completes work new film, ‘77 Bullets’". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ "Mercy Aigbe announces new movie, 77 Bullets". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-01-29. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ Ogala, George (2020-06-20). "Movie Review: Mercy Aigbe’s ‘77 Bullets’: All hype, no substance". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03.
- ↑ "Movie Review: Mercy Aigbe’s ‘77 Bullets’: All hype, no substance". ENigeria Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-20. Archived from the original on 2022-08-03. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Ogala, George (2020-06-20). "Movie Review: Mercy Aigbe’s ‘77 Bullets’: All hype, no substance". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03.
- ↑ "Movie Review: Mercy Aigbe’s ‘77 Bullets’: All hype, no substance". ENigeria Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-20. Archived from the original on 2022-08-03. Retrieved 2022-08-03.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.