African Food Network

African Food Network
TypeÀdáni
Founder(s)Kevin Eze
HeadquartersÀbújá, Nàìjíríà
IndustryOúnjẹ
Websitewww.afrifoodnetwork.com

African Food Network, tí a mọ̀ sí Afri Food Network, jẹ́ ojú òpó wẹ́ẹ́bù àti ilé-iṣẹ́ tí a ṣe fún oúnjẹ àti ìgbé-ayé ilẹ̀ Áfíríkà. Kevin Eze ni ó dá ojú òpó yìí sílẹ̀ ní oṣù January, ọdún 2017 ní Abuja, Nàìjíríà.

Ìtaǹ

African Food Network bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ojúlé ayélujára kan pẹ̀lú ààtò oúnjẹ tí kò tó àádọ́ta ní ọún 2017 tí ó sì ti di ọ̀kan lára àwọn ìwé-àkọsílẹ̀ ààtò oúnjẹ Áfíríkà tó tóbi jùlọ lórí ayélujára pẹ̀lú ààtò oúnjẹ tó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta tí ó ti ọwọ́ àwọn òǹkọ̀wé ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ wá.[1] A dá African Food Network sílẹ̀ láti tún àyípadà ṣe sí ojú tí wọ́n fi ń wo oúnjẹ Áfíríkà ní àgbáyé, àwọn Alásè àti àwọn Alásè oúnjẹ abínibí, èyí tí olùdásílẹ̀ sọ.[2]

Àwọn ayẹyẹ tí wọ́n ṣe

Year Title City Country Ref
2021 Ayẹyẹ Oúnjẹ àti Mímu Áfíríkà Abuja Nigeria [3]
2022 Ayẹyẹ Oúnjẹ àti Mímu Áfíríkà Accra Ghana [4]
2022 Ayẹyẹ Oúnjẹ àti Mímu Áfíríkà Abuja Nigeria [5]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. "Largest online African food recipe database unveiled". Guardian newspaper. Retrieved 23 December 2018. 
  2. "African Food Network to grow African cuisines and chefs globally". Vanguard newspaper. Retrieved 26 November 2017. 
  3. "Day African Food and Drink Festival thrilled food lovers in Abuja". Guardian Newspaper. Archived from the original on 7 October 2021. Retrieved 3 October 2021. 
  4. "African Food Network announces Accra, Ghana as next destination for their festival". Guardian Newspaper. Retrieved 18 January 2022. 
  5. "African Food Festival will be live in Accra, Ghana this year – Co-founder of African Food Network reveals". Vanguard Newspaper. Retrieved 15 January 2022. 

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.