Alaba Jonathan

Alaba Jonathan
Alaba Jonathan

Jonathan at the 2010 FIFA U-20 Women's World Cup
Personal information
OrúkọAlaba Jonathan
Ọjọ́ ìbí1 Oṣù Kẹfà 1992 (1992-06-01) (ọmọ ọdún 34)
Ibi ọjọ́ibíCalabar, Nigeria
Ìga167 cm
Playing positionGoalkeeper
Club information
Current clubPelican Stars
Number16
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Pelican Stars
Bayelsa Queens
National team
Nigeria U-20
Nigeria
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Alaba Jonathan tí wọ́n bí ní ọjọ́ kínní, oṣù kẹfà ọdún 1992, jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ní ìlú Calabar, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù

Alaba Jonathan bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bọ́ùlọ̀lù gbígbá lábẹ́ ẹ̀ka ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ agbábọ́ọ̀lù Navy Angels. Lẹ́yìn tí ó kùnà láti pegedé sínú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù àgbà ikọ̀ tí Navy Angels ni ó lọ darapọ mo ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Pelican Star ní ọdún 2010 lábẹ́ ìkọwọ́bọ̀wé àdéhùn.[1]

Ipa rẹ̀ nínú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Jonathan jẹ́ ìkan lára ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó sì ti gbà bọ́ọ̀lù lẹ́ẹ̀kan rí fún ikọ̀ náà lẹ́ẹ̀kan rí. Ó ti ṣojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ nínú ìdíje 2011 FIFA èyí tí ó wáyé ní orílẹ̀-èdè Germany gẹ́gẹ́ bí aṣọ́lé [2] Ṣáájú èyí ni ó ti kópa nínú ìdíje U-20 World Cup tí ó wáyé ní ọdún 2010 nínú ikọ̀ ọ̀jẹ́wẹ́wẹ́ U-20 ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. Unknown (2 August 2013). "Futball Galore Media: Pelican Stars upset form books to qualify at the expense of Delta Queens". 
  2. Nordwest-Zeitung (17 June 2011). "Der WM-Kader von Nigeria". www.nwzonline.de. Archived from the original on 1 June 2019. Retrieved 1 June 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "U.S. U-20 WNT Ready To Take On Nigeria In Quarterfinals of 2010 FIFA U-20 Women's World Cup". Archived from the original on 24 May 2013. Retrieved 5 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.