Angwech Colline

Angwech Colline
Member of Parliament for Kioga County, Amolatar District
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíNamasale Subcounty, Amolatar District, Uganda
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUganda Peoples Congress (UPC)
OccupationPolitician, Humanitarian
Known for
  • Country Director, Hope for Humans
  • Work with Invisible Children during the LRA insurgency
  • TEDx New York speaker advocating for LRA war victims
  • Co-founder, Far Away Friends
  • Co-founder, Global Leaders School (educating 500 children in Amolatar District)

Angwech Colline jẹ́ oṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Uganda àti ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ aṣòfin tí a yàn fún agbègbè Kioga ní agbègbè Amolatar, àríwá Uganda. Ó máa mú ise láti oṣù karùn-ún ọdún 2026 sí 2031 ní Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kejìlá ti Uganda.[1][2][3][4] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú tí a ń pè ní Uganda Peoples Congress (UPC).[2][3][5]

Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀

A bi Angwech Colline ni agbegbe Namasale ni agbegbe Amolatar, agbegbe Lango, ariwa Uganda.[6]

Iṣẹ́ ọwọ́

Angwech Colline ṣiṣẹ́ ni ipò Olùdarí fún Ìrètí fún Àwọn Ènìyàn ní orílẹ̀-èdè náà, ijọ kan tí ó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọdé tí wọ́n ní àrùn ìró orí ní àríwá Uganda.[1][7][2][8]

Ó tún ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ijọ kan tí a ń pè ní Invisible Children, ijọ kan tí kìí ṣe ti ìjọba tí ó wà ní Àríwá Uganda tí ó ṣe alabapin nínú títẹ̀lé àwọn ọmọdé tí a jí gbé nígbà ìkọlù Lord's Resistance Army War.[1][2][3][9]

Colline tún kópa nínú ìpàdé TEDx ní NewYork, ó ń gbèjà àwọn tí ogun LRA pa ní àríwá Uganda ní àgbáyé.[1]

Ìgbésí ayé ara ẹni

Òun ni olùdásílẹ̀ àjọ Far Away Friends, ti kìí ṣe ti ìjọba, tí ó fún àwọn ọ̀dọ́ lágbára nípasẹ̀ ìlera, ẹ̀kọ́ fún àwọn ọ̀dọ́, àwọn ìbáṣepọ̀ àṣà-ìṣẹ̀dálẹ̀, àti agbára fún ọrọ̀ ajé.[2][3][10][11]

Ó tún ṣe àtìlẹ́yìn fún ilé-ẹ̀kọ́ Global Leaders, ilé-ẹ̀kọ́ kan tí ó ti fún àwọn ọmọ 500 ní ẹ̀kọ́ tó dára ní agbègbè Amolatar.[1][2][11]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 "How woman beat six men to claim Kioga County MP seat". Monitor. 2026-01-22. Retrieved 2026-02-03.
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 2.5 Opio, Anthony (2026-01-21). "Who Is Angwech Colline, Kyoga Constituency's New MP-Elect (2026–2031)? - Dokolo Post % %". Dokolo Post. Retrieved 2026-02-03.
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 Patrick, Okidi (2026-01-21). "Historic Profile of Hon. Angwech Colline Elected as Kyoga Constituency MP on UPC Ticket". TAYARI NEWS UGANDA. Retrieved 2026-02-03.
  4. "Lango reserves 12 seats for UPC in 12th Parliament". Monitor. 2026-01-29. Retrieved 2026-02-03.
  5. "[tndNews][North's First[news][national][crime]". tndNews, Uganda. 2024-05-20. Retrieved 2026-02-03.
  6. "Support Far Away Friends on ColoradoGives.org". ColoradoGives.org. Retrieved 2026-02-03.
  7. "BBC World Service - Outlook, Fighting Uganda's Nodding Syndrome". BBC. Retrieved 2026-02-03.
  8. hazco.co.uk. "A Question of Humanity". www.journeyman.tv. Retrieved 2026-02-03.
  9. "Not All Heroes Wear Capes..." Far Away Friends. Retrieved 2026-02-03.
  10. "Far Away Friends | Transforming Education in Rural Uganda". Far Away Friends. Retrieved 2026-02-03.
  11. 11.0 11.1 Walls, Kaylee. "Far Away Friends Founders Keep Fighting for Uganda". The Cord News. Retrieved 2026-02-03.

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.