Anne Baxter
| Anne Baxter | |
|---|---|
| Ọjọ́ìbí | Oṣù Kàrún 7, 1923 Michigan City, Indiana, U.S. |
| Aláìsí | December 12, 1985 (ọmọ ọdún 62) New York City, U.S. |
| Resting place | Lloyd Jones Cemetery, Spring Green, Wisconsin |
| Iṣẹ́ | Òṣèrébinrin |
| Ìgbà iṣẹ́ | 1936–1985 |
| Political party | Republican |
| Olólùfẹ́ | John Hodiak (m. 1946; div. 1953) Randolph Galt (m. 1960; div. 1969) David Klee [1](m. 1977; died 1977) |
| Àwọn ọmọ | 3 |
| Àwọn olùbátan | Frank Lloyd Wright Lloyd Wright (uncle) John Lloyd Wright Eric Lloyd Wright Elizabeth Wright Ingraham |
| Awards | Ebun Akademi (1947) Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture|Golden Globe Award for Best Supporting Actress (1947) |
Anne Baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kaarun ọdún 1923 , tí o si dágbére fáye ni ọjọ́ kéjììlá, oṣù kéjììlá, ọdún 1985.[2] Ó jẹ́ òṣèrébinrin to gba Ebun Akademi ti Obinrin Osere Keji Didarajulo nígbà áye rẹ̀.
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
Anne Baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje, oṣù kaarun ọdún 1923 ní ìlú Michigan, Indiana si idìlé Catherine Dorothy (née Wright; 1894–1979). Olúlú Westchester County, New York ni wón ti wo dàgbà.
Àwọn Ẹbùn ati Amì Ẹyẹ
| Year | Award | Category | Work | Result |
|---|---|---|---|---|
| 1947 | Golden Globe Award | Best Supporting Actress – Motion Picture | The Razor's Edge | Gbàá |
| 1946 | Ebun Akademi | Best Supporting Actress[3] | The Razor's Edge | Gbàá |
| 1951 | Best Actress | All About Eve | Wọ́n pèé | |
| 1957 | Laurel Award | Topliner Female Dramatic Performance | The Ten Commandments | Gbàá |
| 1969 | Primetime Emmy Award | Outstanding Single Performance by an Actress in a Leading Role | The Name of the Game ("The Bobby Currier Story") | Wọ́n pèé |
Itokasi
- ↑ "Actress Anne Baxter Dead at 62". AP NEWS. December 13, 1985. Retrieved August 26, 2022.
- ↑ "- Turner Classic Movies". Turner Classic Movies. August 23, 2022. Retrieved August 26, 2022.
- ↑ "Oscar-Winner Anne Baxter Is Dead at 62". Washington Post. December 13, 1985. Retrieved August 26, 2022.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.