Apoti
Àpọ́tí jẹ́ ohun ìjókòó tí ó ní orí pẹrẹsẹ tí a fi igi tàbí pákó ṣe. Ẹnìkan ṣoṣo péré ni àpótí lè gbà lórí ìjókòó kan, bákan náà ni kò ní igun tí a lè gbé ọwọ́ lé lọ́tún tàbí lósì. Ó ma ń ní ẹsẹ̀ méjì, mẹ́ta tàbí mẹ́rin, èyí dá lórí agbègbè tí a bá ti ríi. A kò lè sọ wípé àga ni àpótí, nítorí àì ní apá tàbí igun tí a lè fí ọwọ́, tàbí fi ẹ̀yìn tì sí.
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Apoti stool". HOG Furniture. 2021-07-26. Archived from the original on 2021-07-26. Retrieved 2021-07-26.
- ↑ "What does apoti mean in Yoruba?". WordHippo. 2009-02-19. Retrieved 2020-03-03.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.