Awujale
Awùjalẹ̀̀ ni orúkọ oyè Ọba ìbílẹ̀ Ìjẹ̀bú. Ẹni tó bá wà ní ipò yìí ni wọ́n ń pè ní Awùjalẹ̀ ti Ìjẹ̀bú.[1] Awùjalẹ̀ tó wà lórí oyè lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ọba Sikiru Kayode Adetona Ògbágbá Kejì, tí ó wá láti ìdílé Anikinaiya.
Nínú ìwé òfin ti àwọn lọ́balọ́ba tó ń ṣàkóso ìlú Ìjẹ̀bú, àwọn ìdílé Ọlọ́ba mẹ́rin ni ó wà:[2]
- Ìdílé Gbelegbuwa
- Ìdílé Anikinaiya
- Ìdílé Fusengbuwa
- Ìdílé Moyegeso
Ọjọ́ kìíní oṣù kẹsàn-án ọdún 1959 ni wọ́n fi èyí lélẹ̀.
Àtòjọ àwọn Awujale tó ti jẹ sẹ́yìn
- OBA OLU-IWA
- OBA OSHIN
- OBANTA – 1430
- OBA GURU – 1445
- OBA MUNIGBUWA – 1455
- OBANTA II – 1460
- OBA LOJA – 1470
- OBA LOFIN – 1482
- OBA APASA – 1496
- OBA GANJU – 1508
- OBA TEWOGBOYE – 1516
- OBA RUWAMUDA – 1520
- OBA OFINRAN – 1532
- OBA LAPENGBUA – 1537
- OBA OTUTUBIOSUN – 1537
- OBA MOKO IDOWA AJUWAKALE – 1540
- OBA ADISA – 1552
- OBA JEWO – 1561
- OBA ELEWU ILEKE – 1576
- OBA OLUMISODAN ELEWU ILEKE – 1590
- OBA MASE – 1620
- OBA OLOTUSESO – 1625
- OBA MOLA – 1635
- OBA AJANA – 1642
- OBA ORE OR GADEGUN – 1644 (The first female Awujale)
- OBA GUNWAJA – 1655
- OBA JADIARA OR OLOWOJOYEMEJI – 1660
- OBA SAPOKUN – 1675
- OBA FALOKUN – 1687
- OBA MEKUN – 1692
- OBA GBODOGI – 1702
- OBA OJIGI AMOYEGESO – 1710
- OBA LIYEWE AROJOFAYE – 1730
- OBA MOYEGE OLOPE – 1730
- OBA OJORA – 1735
- OBA FESOJOYE – 1745
- OBA ORE JEJE – 1749 (Female)
- OBA SAPENNUWA RUBA KOYE – 1750 (Female)
- OBA ORODUDU JOYE – 1755
- OBA TEWOGBUWA I – 1758
- OBA GBELEGBUWA I – 1760
- OBA FUSENGBUWA – 1790
- OBA SETEJOYE – 1820
- OBA ANIKILAYA FIGBAJOYE AGBOOGUNSA – 1821
- OBA AFIDIPOTEMOLE ADEMUYEWO – 1850
- OBA ATUNWASE ADESINBO – 1886
- OBA OGBAGBA AGBOTEWOLE I – 1895
- OBA FUSIGBOYE ADEONA – 1906
- OBA FESOGBADE ADEMOLU – 1916 (Dethroned)
- OBA ADEKOYA ELERUJA – 1916
- OBA ADEMOLU FESOGBADE – 1917 (Enthroned again)
- OBA ADENUGA AFOLAGBADE – 1925
- OBA OGUNNAIKE FIBIWOJA – 1929
- OBA DANIEL ADESANYA GBELEGBUWA II – 1933-1959
- OBA Dr. SIKIRU OLUWAKAYODE ADETONA, OGBAGBA AGBOTEWOLE II – 1960–present
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Ijebu History". ijebumn.org. Archived from the original on 27 January 2017. Retrieved 30 June 2022. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ "Ijebu Community Association | History". Archived from the original on 13 March 2016. Retrieved 26 February 2016. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.