Deep Roy
| Deep Roy | |
|---|---|
Roy ní Florida SuperCon ti ọdún 2014 | |
| Ọjọ́ìbí | Mohinder Purba 1 Oṣù Kejìlá 1957 Nairobi, Kenya Colony |
| Orúkọ míràn | Gurdeep |
| Iṣẹ́ |
|
| Ìgbà iṣẹ́ | 1976–present |
| Height | ruben aguirre is 6’7” |
| Olólùfẹ́ | Millie Farris (m. 2014) |
Gurdeep Roy (orúko ibí rẹ̀ ni Mohinder Purba; tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù Kejìlá ọdún 1957), tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí Deep Roy, jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Kenya àti Britain. Nítorí pé ko ga tàrà(gíga rẹ̀ ko ju 132 centimetres (4 ft 4 in) lọ,[1] ó ma ń sábà kópa àwọn ènìyàn tí kò ga nínú àwọn eré, bí àpẹẹrẹ gẹ́gẹ́ bi Teeny Weeny nínú The NeverEnding Story àti Oompa-Loompas nínú Charlie and the Chocolate Factory, Keenser in Star Trek, àti nínú àwọn eré bi The X-Files, Doctor Who, àti Eastbound & Down.
Nípa ayé àti Iṣẹ́ rẹ̀
Wọ́n bí Roy ní ọjọ́ kínní oṣù Kejìlá ọdún 1957[2] níNairobi[3] sínú ìdílé India(àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè India). Ó lọ ilé-ìwé láti kọ́ nípa ìṣirò ní London kí ó tó fi ilé ìwé sílè nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún méjìdínlógún. Ó padà lọ The Slim Wood. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré perewu ní ọdún 1976 nínú ìsòrí kẹrindínlọ́gọ́rin eré The New Avengers, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Target!", ó kópa gẹ́gẹ́ bi Klokoe. Ó ṣeré ní ọdún kan náà nínú eré The Pink Panther Strikes Again. Àwọn eré míràn tí ó ti farahàn láti ìgbà náà ni Doctor Who, Star Wars: The Empire Strikes Back, Greystoke: The Legend of Tarzan, Lord of the Apes, Planet of the Apes (2001), Big Fish (2003), Corpse Bride (2005), Charlie and the Chocolate Factory (2005).[4], The X-Files, Flash Gordon, Return to Oz (gẹ́gẹ́ bi Tin Woodman), The Dark Crystal, The NeverEnding Story, Alien from L.A., Howling VI: The Freaks, Return of the Jedi gẹ́gẹ́ bi Droopy McCool.[5], Transformers: Revenge of the Fallen (2009), Star Trek, Star Trek Into Darkness àti Star Trek Beyond àti àwọn eré míràn.
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ Abramovitch, Seth (25 August 2016). "Little People, Big Woes in Hollywood: Low Pay, Degrading Jobs and a Tragic Death". Hollywood Reporter. Retrieved 11 March 2023.
- ↑ "Famous Birthdays". Minneapolis Star Tribune: p. A2. December 1, 2017none; "Today's Birthdays". The Baltimore Sun: p. A9. December 1, 2014.
- ↑ "Roy | Star Trek". StarTrek.com. CBS Television Distribution and CBS Interactive Inc. Retrieved 30 April 2021.
- ↑ Scott, A. O. (15 July 2005). "Film review: Looking for the Candy, Finding a Back Story". The New York Times. https://movies.nytimes.com/2005/07/15/movies/15char.html.
- ↑ "Deep Roy - IMDb". IMDb.com. IMDb, Inc. Archived from the original on 17 October 2012. Retrieved 30 April 2021.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.