Draw soup
Okro soup | |
| Alternative names | Okra soup |
|---|---|
| Type | Soup |
| Main ingredients | Okra, ogbono seeds or ewedu leaves |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
| |
Ọbẹ̀ẹ́yọ̀ jẹ́ orúkọ àwọn ọbẹ̀ ní Gúúsù ìlàòrùn àti Gúúsù ìwọ̀òrùn Nàìjíríà[1] tí a fi ilá, ọ̀gbọ̀nọ̀ (Irvingia gabonensis), tàbí ewédú sè.[2] Orúkọ ọbẹ̀ yíì wá láti bí ọbẹ̀ náà ṣe ki tí ó sì tún fà nínú àwo nígbà tí a bá ń jẹ ẹ́tàbí nígbà tí a bá ń fi ọ̀kèlè bíi(fùfú[3] ijẹ ẹ́ IA lè fi orísìírísìí òkèlè jẹ ẹ́ eíi ba (garri) aàtipiyán Ewwédú [4] ṣe é fi se ọ̀bẹ̀ Yorùbá tí a máa ń jẹ pẹ̀lú Àmàlà.
bésẹ̀ sísèg Àwọn èrọ̀jà ọbẹ̀ẹ́yọ̀ ni:
- Ilá
- Ọ̀gbọ̀nọ̀[5] (wọ̀fún)
- Ẹ̀fọ́ Ugu
- Ewé Uziza
- Irú
- Ata
- Edé[6]
- Ogiri okpei (wọ̀fún)[5]
- Ẹran
- Ẹja
- Epo pupa[7]
Tún wo
- Ewédú
- 3ist of African dishes
- Okra
- Ogbono soup
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ ImmaculateBites (2022-04-06). "Ogbono Soup". Immaculate Bites (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31.
- ↑ "How To Cook Ogbono Soup | Nigerian Draw Soup Recipe". All Nigerian Foods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31.
- ↑ "fufu | food | Britannica". www.britannica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31.
- ↑ "Ewedu - Jute Leaves Soup". Chef Lola's Kitchen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-05. Retrieved 2022-08-31.
- ↑ 5.0 5.1 vanguard (2019-06-13). "Traditional dishes going into extinction are back". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31.
- ↑ ""By Their Foods, Ye Shall Know Them"". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-03. Archived from the original on 2022-09-24. Retrieved 2022-08-31.
- ↑ Rapheal (2018-05-31). "Which oil is best for you? (1)". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31.
Líìnkì
- Babawilly's Dictionary of Pidgin English Words and Phrases. Archived 2006-11-05 at the Wayback Machine.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.