Femi Osofisan

| Femi Osofisan |
|---|
Babáfẹ́mi Adéyẹmí Òsófìsán, tí wọ́n tún máa ń pè ní Fẹ́mi Òsófìsàn tàbí F.O
Listen jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndìnlógún, oṣù kẹfà, ọdún 1946, jẹ́ òǹkọ̀wé, lámèyítọ́ eré tíátà. Wọ́n mọ̀ ọ́n sí oníṣẹ́ lámèyítọ́ àwùjọ ilẹ̀ Áfíríkà nínù àwọn eré àpilẹ̀kọ rẹ̀. Púpọ̀ nínú àwọn àpilẹ̀kọ tí ó ti kọ ni ó máa ń dá lé àgbéyẹ̀wò ire àti ibi. Fẹmi jẹ àfìtàn-kọ́ni-níwà tí àwọn àpilẹ̀kọ rẹ̀ máa ń wá àtúnṣe àti ojútùú sí ìbàjẹ́ àwùjọ. Ó ti kọ ewì lábẹ́ ìnagijẹ Okinba Launko.[1]
Àwọn àṣàyàn iṣẹ́ rèé
- Kolera Kolej. New Horn, 1975.[citation needed]
- The Chattering and the Song. Ibadan: Ibadan University Press, 1977.
- Morountodun and Other Plays. Lagos: Longman, 1982.
- Minted Coins (poetry), Heinemann, 1987.
- Another Raft. Lagos: Malthouse, 1988.
- Once upon Four Robbers. Ibadan: Heinemann, 1991
- Twingle-Twangle A-Twynning Tayle. Longman, 1992.
- Yungba-Yungba and the Dance Contest: A Parable for Our Times, Heinemann Educational, Nigeria, 1993.
- The Album of the Midnight Blackout, University Press, Nigeria, 1994.
- "Warriors of a Failed Utopia? West African writers since the 70s" in Leeds African Studies Bulletin 61 (1996), pp. 11–36.
- Tegonni: An African Antigone. Ibadan: Opon Ifa, 1999.
- "Theater and the Rites of 'Post-Negritude' Remembering". Research in African Literatures 30.1 (1999): 1–11.
- "Love's Unlike Lading: A Comedy from Shakespeare". Lagos: Concept Publications. 2012
- "One Legend, Many seasons". Lagos: Concept Publications. 2001
Àmín ẹ̀yẹ
- 2015: PAWA Membership Honorary Award[2][3]
- 2016: Thalia Prize from the International Association of Theatre Critics[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "As Osofisan's 'Cordelia' goes on big screen | The Nation". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-25. Retrieved 2021-07-07.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>tag; no text was provided for refs named "PAWA". - ↑ "Echoes of Achebe's works at writers' show". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-11-24. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ "Femi Osofisan wins Thalia Prize 2016". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-02-08. Retrieved 2020-05-30.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.