Finding Hubby

Finding Hubby jẹ èrè fílmù ire ìfẹ tí a ṣe lati ọwọ Femi Ogunsanwo awon akopa ninu ere na ni Kehinde Bankole, Munachi Abii, Ade Laoye, and Omowunmi Dada . O jẹ aṣamubadọgba iboju ti bulọọgi ti Tunde Leye kọ. [1][2]

Idite

Finding Hubby sọ itan ti Oyin Clegg, omidan kan ti o je ọmọ ọdún 35 ati awọn ọrẹ rẹ bi wọn ṣe sa ipa won lati wa ololufẹ won ni ilu Eko, ni orile-ede Naijiria. [1]

Awọn akopa ninu eré

  • Ade Laoye gẹgẹ bi Oyin Clegg
  • Munachi Abi gẹgẹ bi Gloria
  • Kehinde Bankole gẹgẹ bi Toke
  • Teniola Aladese gẹgẹ bi Tosan
  • Omowunmi Dada gẹgẹ bi Moroti Hassan
  • Efa Iwara gẹgẹ bi Adefemi Omotosho
  • David A. Apemiye gege bi Olusoagutan Mama Oyin
  • Samuẹli Asaa gẹ́gẹ́ bí DG
  • Folarin Bankole gẹgẹ bi Rude Guy ni Club
  • Demi Banwo gẹgẹ bi Olumide
  • Sammy Eddy gẹgẹ bi Aminu
  • Oludara Egerton-Shyngle gẹgẹ bi Iyawo Desmond
  • Charles Etubiebi gẹgẹ bi Ossy
  • Maryann Eziekwe gẹgẹ bi Olusoagutan PA
  • Chris Isibor gẹgẹ bi Ogbeni Kalu
  • Ogunji Tolulope Joy gẹgẹ bi PA to Oyin's Mama

Ṣiṣejade ati idasilẹ

Finding Hubby da lori bulọọgi ṣiṣe ntẹle ti Tunde Leye kọ eyiti o jade laarin Oṣu Kẹrin ati Oṣu Kẹsan ọdún 2012. O si jade ni awọn sinima orilẹ-ede Nàìjíríà ni ọjọ 4 Oṣu kejila ọdun 2020. Won gbejade lori Netflix ni ọjọ 9 Oṣu Keje ọdun 2021. .[3] It was released on Netflix on 9 July 2021.[2]

Gbigbawọle

Alariwisi Nollywood kan ṣapejuwe Finding Hubby gẹgẹ bi “ere kan ti o fi ọgbọn yànnàná awọn idojuko ti ọdọ ri nígbàkugba.20-12-02|title=Femi D.Ogunsanwo and Tunde Leye unveil “Finding Hubby” to raving reviews|url=https://guardian.ng/art/c74-arts/femi-d-ogunsanwo-and-tunde-leye-unveil-finding-hubby-to-raving-reviews/%7Curl-status=live%7Caccess-date=2021-10-04%7Cwebsite=The[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] Guardian Nigeria News - Nigeria and World News|language=en-US}}</ref> It was rated 4 out of 10 by the movie reviewer, Martin Cid.[4] O jẹ ipò 4 larin fíìmù 10 nipasẹ oluyẹwo fiimu, Martin Cid. [5]

Awọn itọkasi

 

  1. 1.0 1.1 Augoye, Jayne (2020-09-19). "Kehinde Bankole, Munachi Abii, others to star in ‘Finding Hubby’" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-04.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. 2.0 2.1 "'Finding Hubby' to hit Netflix July 9". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-25. Retrieved 2021-10-03. 
  3. Dayo, Bernard (2020-12-02). "Nneka the Pretty Serpent, Omo Ghetto, Finding Hubby". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-10-04. Retrieved 2021-10-04. 
  4. "Finding Hubby (2020). Netlfix Movie - Martin Cid Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-09. Archived from the original on 2021-10-04. Retrieved 2021-10-04. 
  5. "Finding Hubby (2020). Netlfix Movie - Martin Cid Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-09. Archived from the original on 2021-10-04. Retrieved 2021-10-04. 

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.