Grokipedia
Grokipedia jẹ́ ìkànnì ìwé ìmọ̀-ọ̀fẹ́ lórí pẹpẹ ayélujára tí wọ́n sọ wípé pẹ́pẹ́ ọgbọ́n àpìlẹ̀rọ ayélujára XAI tí Elon Musk ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀. Wọ́n ní Elon Musk ní òun dá a sílẹ̀ láti pèsè imọ̀ àgbọ́nọ̀ngbẹ́ àìṣègbè fẹ́nìkan lórí pẹpẹ ayélujára, nítorí òun gbà pé Wikipedia kò fi bẹ́ẹ̀ ṣàìṣègbè[1][2][3]
Ìpìlẹ̀
Lọ́pọ̀ ìgbà ni Elon Musk ti ń sọ pé òun yóò pẹpẹ imọ̀ àgbọ́nọ̀ngbẹ́ ayélujára tí yóò dára jù wikipedia lọ.[4] Ó ṣàlàyé pé ọ̀pọ̀ nínú àwọn ìwé Ìtọ́kasí tí Wikipedia sọ pé wọn ṣe é gbára lé ní kò rí bẹ́ẹ̀, pàápàá jùlọ wọ́n kò ṣe dáadáa tó fún Ìtọ́kasí fún ìròyìn tí kò fẹ́ ìyípadà. [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ Oremus, Will; Siddiqui, Faiz (2025-10-27). "Elon Musk launches a Wikipedia rival that extols his own ‘vision’". The Washington Post. Retrieved 2025-10-30.
- ↑ 2.0 2.1 Yasseri, Taha (2025-10-15), Grokipedia: Elon Musk is right that Wikipedia is biased, but his AI alternative will be the same at best, The Conversation, doi:10.64628/ab.s75tmpjmh
- ↑ "Elon Musk launches Grokipedia as an alternative to 'woke' Wikipedia". NBC News. 2025-10-28. Retrieved 2025-10-30.
- ↑ Contreras, Cesareo (2025-10-14). "Can Elon Musk’s Grokipedia compete with Wikipedia? An expert explains". Northeastern Global News. Retrieved 2025-10-30.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.