Ibrahim Chatta
Ibrahim Chatta ( tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹwàá ọdún 1970) jẹ́ gbajúgbajà olùdarí àti òṣèrè sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá láti Ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀ Nàìjíríà .[1]
Ìgbé-ayé Rẹ̀ Ní Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹ̀pẹ̀
Ibrahim Chatta kò fi bẹ́ẹ̀ kàwé pùpọ́. Ìpele kẹta ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ńdìrì ní ó ti fi ẹ̀kọ́ kíkà sílẹ̀. Ò wá pápá kẹ́kọ̀ọ́ lóríṣiríṣi nípa ère sinimá àgbéléwò. Kí ó tó di ìlúmọ̀ọ́ká, ọ̀pọ̀ ni iṣẹ́ ló tí ṣe. Àkọsílẹ̀ kan sọ pé ó ti fìgbà kan ṣíṣe apèròsọ́kọ̀. [2]
Àwọn Ìtọ́kasi
- ↑ Olatunji, Dami (2018-08-15). "Top facts from the biography of a Nollywood actor Ibrahim Chatta". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-10-21.
- ↑ "Ibrahim Chatta Biography: Age & Movies". 360dopes. 2018-07-14. Retrieved 2019-10-21.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.