Ini Archibong

Inimfon "Ini" Joshua Archibong tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù Karùn-ún ọdún 2938 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà tí ó sì tún jẹ́ oníṣẹ́-ọnà àti ayàwòrán. [1][2] Iṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ iṣẹ́-ọnà tó pegedé,jùlọ tí ó sì nííṣe pẹ̀lú ìmọ̀ tẹkinọ́lọ́jì ìròrí, ẹ̀sìn agbáyé àti ìsirò.[3][4]

Inẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

Wọ́n bí Ini ní agbègbè Pasadena ní California sínú ẹbí tọkọ-taya tí wọ́n jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n rí ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ gbà lọ sí orílẹ̀-èdè Amerika.[2][5] Ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ Polytechnic School tí ó wà ní ìlú California, lẹ́yìn náà ni ó l9 sílé ẹ̀kọ́ Fásitì ìmò ìṣirò ti University of Southern California ṣáájú kí ó tó filé ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀ láì parí[6][7][8] Lẹ́yìn èyí ni ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ ArtCenter College of Design níbi tí ó ti rí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ Edwards Entrance Scholar àti ti Art Center Outreach Grant gbà, òun ni wọ́n sì dárúkọ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí "akẹ́kọ̀ọ́ tí iṣẹ́-ọnà rẹ̀ wàyàmì jùlọ ní ọdún 2010", [9] ilé ẹ̀kọ́ yí náà ló sì ti gba oyè nínú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa àwùjọ.[10][11]

Ó darapọ̀ mọ́ Tim Kobe's Eight Inc. [de] ní ìlú Singapore, lẹ́yìn tí ó kàwé gboyè ṣá ṣáájú kí ó tó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ nílé ẹ̀kọ́ École cantonale d'art de Lausanne (ÉCAL), níbi tí ó ti kọ́ nípa Design for Luxury and Craftsmanship tí ó sì gba oyè dìgírì kejì nínú ìmọ̀ yí kan náà.[12][13][14]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. "Designer Ini Archibong Shares a Glimpse Into His World, in Photographs" (in en-US). The New York Times. 2019-03-21. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2019/03/21/t-magazine/ini-archibong.html. 
  2. 2.0 2.1 Swithinbank, Robin (2019-03-20). "A Hermès Watch for Any Gender". The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2019/03/20/fashion/watches-ini-archibong-hermes.html. 
  3. "The Breakout Year of Ini Archibong". Surface magazine. 2019-09-23. Retrieved 2021-03-26. 
  4. "Ini Archibong | Connected". connectedbydesign.online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-04-20. Retrieved 2021-03-26. 
  5. Olley, Cat (2022-03-02). "Ini Archibong introduces us to his all-time favourite object". ELLE Decoration (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-26. 
  6. "Poly Alumni Association nominates 2019 Distinguished Alumnus – Ini Archibong '01". Polytechnic School. 2019-07-23. Retrieved 2022-09-28. 
  7. Didero, Maria Cristina. "Interview with Ini Archibong, artist of the future-present". Domus (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-26. 
  8. London, Eli (2022-10-19). "Ini Archibong: a multi-disciplinary master of design". Courier (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-01. Retrieved 2022-12-01. 
  9. Gold, Jered (2010-05-05). "Archibong Named Student Designer of the Year". ArtCenter News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-26. 
  10. "Ini Archibong". ArtCenter College of Design. Retrieved 2022-09-28. 
  11. "How Los Angeles Shaped Ini Archibong's Unique Design Vision". Azure. 2019-02-22. Retrieved 2021-03-26. 
  12. "Introducing Ini Archibong, Hermès' Latest Watchmaking Wunderkind". British Vogue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 13 January 2019. Retrieved 2021-03-26. 
  13. "INTERVIEW: Designer Ini Archibong On Making "Three-Dimensional Poetry"". Pin-Up Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-26. 
  14. "WDO | Changemakers 2022: Ini Archibong is Making Space for Design Storytelling". World Design Organization (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 December 2022. Retrieved 2023-03-13. 

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.