Levi
| Levi | |
|---|---|
| Fáìlì:Levi poster.jpg | |
| Òǹkọ̀wé | Bethrogers |
| Àwọn òṣèré | Ramsey Nouah Nancy Isime Deyemi Okanlawon Lydia Forson Bimbo Manuel |
| Orin | Abiola |
| Ìyàwòrán sinimá | Okechukwu Oku |
| Olóòtú | Okey Oku |
| Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Oracle Films Okey Oku Films |
| Déètì àgbéjáde |
|
| Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
| Èdè | English |
Levi jẹ́ eré oníṣé tí wọ́n ṣe àgbéjáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2019 Okechukwu Oku ni olùdarí eré náà. Àwọn ìràwọ̀ òṣèré tí wọ́n kópa nínú eré náà ni Ramsey Nouah, Nancy Isime, Deyemi Okanlawon, Lydia Forson àti Bimbo Manuel.[1][2]
Ìsọníṣókí
Wọ́n fi àkòrí eré náà sọrí olú ẹ̀dá ìtàn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Levi, ẹni tó pinnu láti lọ wá ìfẹ́ ìgbà ewe rẹ̀, Somi,lẹ́yìn tí wọ́n ṣe àyẹ̀wò ìlera rẹ̀ tí wọ́n sì rí i pé ó ní àìsàn tó lewu tó lè gba ẹ̀mí rẹ̀, kí wọ́n lè wà pọ̀ nikẹhin kí ó tó kú . Ṣùgbọ́n, Somi ti ní ọkọ tẹ́lẹ̀, síbẹ̀ Levi kò fẹ́ gba ìjákulẹ̀.
Àwọn Òṣèré Akópa
- Ramsey Nouah kópa gẹ́gẹ́ bíi Levi
- Joseph Benjamin kópa gẹ́gẹ́ bíi Jasper
- Nancy Isime kópa gẹ́gẹ́ bíi Somi
- Deyemi Okanlawon kópa gẹ́gẹ́ bíi Isreal
- Lydia Forson kópa gẹ́gẹ́ bíi Ọ̀gá
- Bimbo Manuel kópa gẹ́gẹ́ bíi Dọ́kítà
- Mordiyyah Obani kópa gẹ́gẹ́ bíi Èjìrẹ́
- Rodiyyah Obani kópa gẹ́gẹ́ bíi Èjìrẹ́
- Chinazor Anuo kópa gẹ́gẹ́ bíi Dọ́kítà Obìnrin
- Chinenye Nnaji kópa gẹ́gẹ́ bíi office extra
- Charles Murphy Iwuchukwu kópa gẹ́gẹ́ bíi Èṣọ́
- Kingsley Okoye Rex kópa gẹ́gẹ́ bíi office extra
- Maxwell Nebo kópa gẹ́gẹ́ bíi Olóyè Obi
- Shire Nwachukwu kópa gẹ́gẹ́ bíi Gana
- Lisa Omorodion kópa gẹ́gẹ́ bíi Ebere
- Nneoma Okoro kópa gẹ́gẹ́ bíi Nọ́ọ̀sì
- Bolaji Ogunmola kópa gẹ́gẹ́ bíi Gina
Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ àti Ìforúkọsílé
| Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ẹ̀ka | Èsì | Ìtọ́kasí |
|---|---|---|---|---|
| 2019 | Best of Nollywood Awards | Olú òṣèré akópa tó peregedé jùlọ– Ẹ̀ka Gẹ̀ẹ́sì | Wọ́n pèé | [3] |
| Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Olú òṣèré tó dára jù lọ – Ẹ̀ka Gẹ̀ẹ́sì | Gbàá | |||
| Eré tó ní àgbékalẹ̀ ìtàn tó dára jù lọ | Wọ́n pèé | |||
| Eré tí wọ́n ṣe àfihàn rẹ̀ jù lọ ní Cinema | Wọ́n pèé | |||
| Eré tó dára jù lọ | Wọ́n pèé | |||
| Olùdarí eré tó dára jù lọ | Wọ́n pèé | |||
| Eré tó ní ohùn abẹ́lẹ̀ tó dára jù lọ | Wọ́n pèé |
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ Dayo, Bernard (2019-01-09). "Ramsey Nouah is frightening in the trailer for 'Levi' and this may be the best we have ever seen him » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-19.
- ↑ nollywoodreinvented (2019-01-07). "COMING SOON: LEVI". Nollywood Reinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-19.
- ↑ Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition" (in en). Pulse Nigeria. https://www.pulse.ng/entertainment/movies/bon-awards-2019-gold-statue-gabriel-afolayan-win-big-at-11th-edition/4d0w2n4.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.