Manhattan Project
| Agbegbe Manhattan | |
|---|---|
Ise agbese Manhattan ti da bombu iparun. akoko ni gbogbo ayé Awon idanwo Trinity je fi han. | |
| Ìgbéṣe | 1942–1946 |
| Orílẹ̀-èdè | |
| Ẹ̀ka | United States Army Corps of Engineers |
| Ibùjokòó | Oak Ridge, Tennessee |
| Àjọ̀dún | 13 August 1942 |
| Engagements | Allied Invasion of Italy Allied Invasion of France Allied Invasion of Germany Atomic bombings of Hiroshima and Nagasaki Allied Occupation of Japan |
| Disbanded | 15 August 1947 |
| Àwọn apàṣẹ | |
| Notable commanders |
Kenneth Nichols |
| Àmì-ẹ̀ṣọ́ | |
| Shoulder patch that was adopted in 1945 for the Manhattan District | |
| Manhattan Project emblem (unofficial) | |

The Manhattan Project tumo si ni èdè Yoruba je (Ise agbese Manhattan) ti n je oruko fun ise ti akojopo ni Ogun Agbaye Keji nigba ti won ti gbiyanju lati seda bombu atomu akoko. Orile-ede Amerika lo lewaju iseowo yi pelu ikopa Britani ati Kanada.
J. Robert Oppenheimer ti je èniyàn ti o ti ran Amerika lowo lati ko bombu atomiki.
Kini je awon bombu iparun tabi bọmbù átọ́mù?
Awon bombu iparun ati bọmbù átọ́mù je awon ohun ti o le parun awon opolopo ohun. Awon bombu iparun lewu gidigan, nitori ti e ba lo awon bombu iparun, ti e ba ti pari, e ko ma ri kankan, nitori bombu iparun won parun ohun gbogbo.
Awon bombu ipraun ewu ju ibon, ọrun ati ọfà, kànnàkànnà, opa, òkò, ati gbogbo ohun ijagun ni gbogbo ayé. Awon bombu ipraun lewu gidigan!
Se awon orile-ede ni awon bombu iparun (bọmbù átọ́mù)?
Ah, bee ni oh! Awon orile-ede dabi Amerika, China, Russia, Israeli, won ni awon bombu iparun sùgbon Afrika, won ko ni awon bombu iparun nitori won fe se itoju ti agbayé wa.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.

