May D
| May D | |
|---|---|
| Ọjọ́ìbí | Akinmayokun Awodumila [1] Delta State, Nigeria |
| Orúkọ míràn | Mr May D |
| Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
| Iṣẹ́ | Singer, songwriter, dancer |
| Ìgbà iṣẹ́ | 2011–present |
| Musical career | |
| Irú orin | Afropop, R&B, house, Afrobeat |
| Labels | Confam Entertainment Davido Music Worldwide |
| Associated acts |
|
Akinmayokun Awodumila (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 28, oṣù December, ní ọdún 1984[2]), tí wọ́n tún mọ̀ sí May D, jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà. Ó fìgbà kan wà ní ìtẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú R&B àti Square records, èyi tí àwọn P-Square.
Ìgbésí ayé ìbéèrè àti ẹ̀kọ́
Wọ́n bí May D ní Akinmayokun Awodumila ní ìlú Èkó, ó sì jẹ́ ọmọ méje. Ó lọ sí Yunifásítì ti Èkó, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbánisọ̀rọ̀ gbogbogbòò
Ó di olókìkí ní ọdún kan náà tí ó fọwọ́ sí ìwé àkọlé Square Records, ní ọdún 2011.[3] Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹjọ ọdún 2012, wọ́n kéde pé May D kò sí nínú ìwé àkọlé mọ́, gẹ́gẹ́ bí Premium Times news ṣe sọ.[4][5]
Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún 2011, May D gbé orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde "Soundtrack" nípasẹ̀ ilé iṣẹ́ Square Records. Fídíò orin náà, tí Clarence Peters darí, ni a gbé jáde ní ọjọ́ kejìlá oṣù kíní ọdún 2012.[6][7] Fídíò náà ní ìwòye tó ju mílíọ̀nù mẹ́wàá lọ lórí ikanni YouTube wọn kí wọ́n tó pa á rẹ́ kúrò nínú ilé iṣẹ́ náà. Ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 2012, May D dá ilé iṣẹ́ orin aládàáni kan tí a mọ̀ sí Confam Entertainment sílẹ̀.[8] Ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù keje ọdún 2020, May D kéde lórí àkọlé Twitter rẹ̀ pé òun ti fọwọ́ sí àdéhùn pẹ̀lú Davido Music Worldwide.[9][10]
Àwọn akojopo orin rẹ̀
Àwọn òrin yàrá ìkà ohùn sílẹ̀ tí and EPs
- Chapter One (2013)[11]
- SUREBOY (2021)[12]
Òrin tí o dako fún rare
| Year | Title | Album | Release date |
| 2011 | "Soundtrack" | Chapter One | 16 May 2013 |
|---|---|---|---|
| 2012 | "Use Me" | ||
| "Ile Ijo" | |||
| "Gat Me High" | |||
| "One Night Stand" | Non-album | ||
| 2013 | "You Want to Know Me" (feat. P-Square) | Chapter One | 16 May 2013 |
| "Ur Eyes" (feat. Davido) | |||
| "So Many Tinz" | |||
| "Love in the Air" | Non-album | ||
| 2014 | "All Over You" | ||
| "Ibadi" | |||
| 2016 | "Bamilo" (feat. Wizkid) | ||
| "Hustle" (feat. Akon and Davido)[13] | Non-album | 24 October 2016 | |
| 2018 | "Love Overdose" | Àdàkọ:TBA | |
| 2019 | "Dada" | Non-album | 21 November 2019 |
| 2020 | "Time for You " | Non-album | 10 February 2020 |
| 2021 | "Dodo " | Non-album | 20 August 2021[14] |
Èyítí o tí farahàn
| Year | Title | Artist name(s) | Album | Release date |
| 2010 | "Farabale" | Show Dem Camp | The Dreamer Project | 18 September 2011 |
|---|---|---|---|---|
| "Eyes On Me" | ||||
| 2011 | "Chop My Money" | P-Square | The Invasion | 29 July 2011 |
| 2012 | "Chop My Money (Remix)" | |||
| "Bless Me" | Davido | Omo Baba Olowo | 17 July 2012 | |
| "Mujo" | Sina Rambo | Non-album | ||
| "Coming for You" | Mo'Cheddah | |||
| "Way You Whine (Remix)" | Dpzle | |||
| "No Time" | DJ Xclusive | |||
| 2013 | "Whine" | Iyanya | Desire | 6 February 2013 |
| "Happiness" | Mafikizolo | Reunited | 10 April 2013 | |
| "Madantin (Remix)" | Jaywon | Oba Orin | 1 April 2016 | |
| "Peperenpe (Remix)" | Klever J | That Klever Jay | 27 March 2015 | |
| "Banger" | Durella | Non-album | ||
| 2014 | "My #1 (Numero Uno)" | DJ Neptune | ||
| "Jigololo" | Eddyaya | |||
| "Give Your Love to Me" | Fliptyce | |||
| "Wiggle" | Mo'Blow | |||
| "Love in the Air (EDM Remix)" | Fliptyce | |||
| 2015 | "Up in the Club" | N6 | ||
| "Amina" | Ikechukwu | |||
| "Birthday Girl" | Samklef |
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "May D – biography". Retrieved 28 September 2016.
- ↑ Inc, Naijakit. "May D's Biography: Age, Songs & Profile » NaijaKit". NaijaKit (in English). Archived from the original on 24 September 2022. Retrieved 22 June 2022.
- ↑ "Square Records Presents May D". notjustOk. 13 May 2011. Archived from the original on 2 October 2016. Retrieved 27 September 2016. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ "Psquare announce split with MayD". Premium Times. 21 August 2012. http://www.premiumtimesng.com/news/97213-psquare-announce-split-with-mayd.html. Retrieved 28 September 2016.
- ↑ "No more together: May-D and P-Square split because of "irreconcilable differences".". Daily Post (Lagos, Nigeria). http://dailypost.ng/2012/08/21/may-d-p-square-split-irreconcilable-differences/. Retrieved 28 September 2016.
- ↑ BellaNaija.com (2020-05-24). "May D Reveals his Alleged Past Ordeal with Former Record Label". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-08.
- ↑ "May D reveals cause of fallout with PSquare - P.M. News". Archived from the original on 2020-05-17. Retrieved 2025-07-01.
- ↑ "May D Launches New Record Label |". 25 September 2012. https://thenet.ng/may-d-launches-new-record-label-confam-entertainment/.
- ↑ "Positive Reactions As Davido Signs May D To DMW Label". 18 July 2020.
- ↑ Mohammed, Farouk (2020-07-18). "Davido signs May D to DMW record label". Okay.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-08.
- ↑ "Chapter One - Album by May D". music.apple.com. 16 May 2013. Retrieved 3 July 2024.
- ↑ "EP: May D – Sureboy". Navdrillnet.com. 15 October 2021. Retrieved 15 October 2021.
- ↑ "May D – Hustle feat. Akon & Davido (Prod. by Mckeezyk) – Daily Post Nigeria". Daily Post (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 28 October 2016. https://web.archive.org/web/20161028140342/http://dailypost.ng/music/2016/10/27/may-d-hustle-feat-akon-davido-prod-mckeezyk/.
- ↑ "[Music] May D – Dodo". Naijaloaded | Nigeria's Most Visited Music & Entertainment Website (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 20 August 2021. Archived from the original on 26 August 2021. Retrieved 26 August 2021. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.