Microlophus
| Microlophus | |
|---|---|
| Microlophus albemarlensis, abo tí ó wọ́pọ̀ ní Galápagos | |
| Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
| Ìjọba: | |
| Ará: | |
| Ẹgbẹ́: | |
| Ìtò: | |
| Ìdílé: | |
| Ìbátan: | Microlophus Duméril & Bibron, 1837
|
| Àwọn ẹ̀yà | |
|
bíi ogún | |
Microlophus jẹ́ ti ìdílé àwọn alángbá Tropidurid ní Gúúsù Amẹ́ríkà. Ogún ẹ̀yà alángbá yìí ni a dámọ̀ tí mẹ́fà sì wọ́pọ̀ ní erúkùṣú Galápagos ní ibi tí wọ́n ti mọ̀ wọ́n sí àwọn alángbá àpáta[1][2] (nígbà míràn wọ́n máa ń kówọn sí àye Tropidurus). Wọ́n má ń rí àwọn tókù tí wọ́n ń pè ní Pacific iguanas, ní Andes lọ́na òkun Chile, Peru, àti Ecuador. Ìrí àwọn alángbá yìí káàkiri àti ìrísí, àwọ̀, àti ìwà tí ó yàtọ̀ ṣe àfihàn nkan tí àwọn olóyìnbo ń pè ní adaptive radiation tí ó ní ṣe pẹ̀lú àwọn tí ó ń gbé ní archipelago yìí. A ma ń rí àwọn ẹ̀yà kan ní gbogbo àárín àtí ìwọ oòrùn àwọn erékuỳṣù tí ó ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àkókó òkun lọlẹ̀ díẹ̀, tí ó sì jẹ́ pé a maa ń rí àwọn ẹ̀yà mẹ́fà kan ní eteetí àwọn erékùṣù. Ó Ṣeéṣe kó jẹ́ wípé ìran kan ní gbogbo àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí ti wá. Síbẹ̀síbẹ̀, Tropiduridae lè pàwọdà, àwọn ẹ̀yà kan náà sí ma ń ní àwọ̀ ọ̀tọ̀tọ̀ ní ibùgbé ọ̀tọ̀tọ̀, tí wọn a sì maa ṣe àfihan àwọ̀ ọ̀tọ̀tọ̀. Àwọn ẹranko tí ó ń gbé ní àpáta dúdú maa n ní àwọ̀ dúdú ju àwọn tó ń gbe ní orí iyẹ̀pẹ̀ tí ó mọ́.
Àwọn ẹ̀yà


Wọ́n tòwọ́n bí ábídí.[3] (* wọ́n wọ́pọ̀ ní àwọn erékùṣù Galapágos).
- Microlophus albemarlensis
- Microlophus atacamensis
- Microlophus bivittatus
- Microlophus delanonis
- Microlophus duncanensis
- Microlophus grayii
- Microlophus habelii
- Microlophus heterolepis
- Microlophus koepckeorum
- Microlophus occipitalis
- Microlophus pacificus
- Microlophus peruvianus
- Microlophus quadrivittatus
- Microlophus stolzmanni
- Microlophus tarapacensis
- Microlophus theresiae
- Microlophus theresioides
- Microlophus thoracicus
- Microlophus tigris
- Microlophus yanezi
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ Fitter, J.;Fitter, D; and Hosking, D. (2000) Wildlife of the Galalpagos.
- ↑ Microlophus, Reptile Database
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.