Mr Real

Mr Real
Orúkọ àbísọOkafor Uchenna Victor
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiRealself
Ọjọ́ìbíLagos State, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Ikeja, Lagos
Irú orin
Occupation(s)
  • Rapper
  • singer
  • songwriter
InstrumentsVocals
Years active2012–present
LabelsSME Africa
Associated acts

Okafor Uchenna Victor, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Mr Real, jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wá láti Ìpínlẹ̀ Èkó.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé ẹ̀

Mr Real tí a tún mọ̀ sí Real self ni a bí ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kẹjọ ní ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, sí àwọn òbí tí ó wá láti ìlú Okija, Ìpínlẹ̀ Anámbra.[1] Ó di gbajúgbajà lẹ́yìn tí ó gbé orin "Legbegbe" jáde.[2] Ó tọwọ́ bọ̀wé fún ṣíṣe ọ̀wọ́ orin pẹ̀lú Sony Music Entertainment Africa ní ọdún 2018.[3]

Àtòjọ orin ẹ̀

Àwọn orin àdákọ

Year Song Featured
2017 Legbebe Idowest, Oba Dice, Kelvin Chuks
2018 Overload Mr Eazi & Slimcase
2018 Allow Me Solidstar
2020 Baba fela

Àwọn orin tí ó kópa nínú rẹ̀

Year Song Artist Featured
2017 Issa Banger D'banj Slimcase
2018 Balu CDQ Idowest
2018 Normal Level DJ Nana Zoro
2018 Sisi DJ Neptune Small Doctor & Pasuma
2018 Masun Jaywon Idowest & Ichaba
2018 Upandan Zoroswagbag
2018 Kunta Kunte[4] DJ Lambo

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

Year Award ceremony Award description Result Ref
2018 The Headies Best Street-Hop Artiste Wọ́n pèé [5]
Year Award ceremony Award description Result Ref
2018 Nigeria Entertainment Awards Hottest Single of the year Gbàá [6]

Àwọn ìtọ́kasí

Content Disclaimer

Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.

  1. The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
  2. There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
  3. It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
  4. Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
  5. Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.