Muhammad Nami
Muhammad Mamman Nami | |
|---|---|
| Alága àjọ Federal Inland Revenue Service | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
| Ó gun orí àga November 2019 | |
| Asíwájú | Babatunde Fowler |
| Àwọn àlàyé onítòhún | |
| Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kejì 1968 Nami, Niger State, Nigeria |
| Education | Bayero University Kano, - (B.A (Hon) Sociology) Ahmadu Bello University, Zaria - (MBA) |
| Occupation | Accountant, tax administrator |
Muhammad Mamman Nami (tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù kejì ọdun 1968) jẹ́ Alága fún àjọ ìjọba-àpapò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń ṣe kòkárí fún owó-orí gbígbà, FIRS. Lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kejìlá ọdún 2019 ni Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ fi orúkọ rẹ̀ ránṣẹ́ sí ilé-ìgbìmọ̀-aṣòfin-àgbà fún ìfọwọ́sí. Nami ni yóò rọ́pò Babátúndé Fowler, tí ó jẹ́ Alága àjọ Federal Inland Revenue Service, FIRS, ṣùgbọ́n tí fẹ̀híntì lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kejìlá ọdún 2019.[1][2]
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
Ọ̀gbẹ́ni Nami jẹ́ gbajúgbajà onímọ̀ nípa owó-orí. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ile iṣẹ́ àti ìjọba lóríṣiríṣi tí Nami tí ṣiṣẹ́ ṣíṣe kòkárí àti ìgbaninímọ̀ràn lórí owó-orí fun. Muhammad Nami kàwé gboyè dìgírì nínú ìmò àyíká (Sociology) ní ifáfitì Bayero University ní ìlú Kano lọ́dún 1991 àti Ahmadu Bello University ní ìlú, Zaria lọ́dún 1991, níbi tí ó ti gba dìgírì kejì, Masters of Business lọ́dún 2004. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Chattered Institute of Taxation of Nigeria, Institute of Debt Recovery Practitioners of Nigeria àti Associate Member of Nigerian Institute of Management (Chartered) pelui Association of National Accountants of Nigeria. [3] [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ Nseyen, Nsikak (2019-12-09). "FIRS: Profile of nominated chairman, Muhammed Nami - Daily Post Nigeria". Daily Post Nigeria. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ "PROFILE: Muhammad Nami, a tax consultant, heads Nigeria's FIRS". Premium Times Nigeria. 2019-12-09. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ Published (2015-12-15). "10 things to know about new FIRS chairman, Muhammad Nami". Punch Newspapers. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ Olaniyi, Joshua Odeyemi & Muideen (2019-12-09). "11 things you should know about Muhammad Nami, Buhari's nominee to head FIRS – Daily Trust". Daily Trust. Retrieved 2019-12-09.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.