Nimbe
Nimbe tí a tún mọ̀ sí Nimbe: Eré náà jẹ́ eré orí-ìtàgé ọdún 2019 Nàìjíríà tí Tope Alake darí rẹ̀. Gbajúgbajà òṣèré fíìmù náà ni Chimezie Imo, Toyin Abraham, Rachael Okonkwo àti Doyin Abiola . [1] asájú oṣere Chimezie Imo ní o kópa olú-èdá ìtàn nínú eré náà àti pé ìtàn náà dá lórí ìlòkulò òògùn. Fíìmù náà ni a gbé jáde sí orí ìtàgé ní Nàìjíríà ní ọjọ́ kọkàndinlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹta ọdún 2019 àti pé o gba àwọn àtúnyẹwò rere láti ọ̀dọ̀ àwọn aláriwisi. [2] Fíìmù náà di wà niwájú láàrín àwọn fíímù tí ó jáde nínú pop box nla àti pé o jẹ ọ̀kan nínú awọn fíìmù àṣeyọrí Nàìjíríà fún ọdún 2019 . Fíìmù náà wà ní ipò kokàndínlọ́gọ́ta 59th ní atokọ gbogbogbò ti àwọn fíìmù ti o n wọlé ga jùlọ ní Naijiria . Wọn tún yan fíìmù náà fún Aamì Ẹ̀yẹ Fíìmù Nólíwùdù UK ti ọdún 2019. [3]
Àwọn òṣèré
- Chimezie Imo gẹ́gẹ́bí Nimbe
- Toyin Abraham gẹ́gẹ́bí Uduak (iya Nimbe)
- Rachael Okonkwo gẹ́gẹ́bí Mira
- Doyin Abiola gẹ́gẹ́bí Peju
- Odunlade Adekola gẹ́gẹ́bí Bayo
- Sani Musa Danja gẹ́gẹ́bí Abu
- Molawa Davis gẹ́gẹ́bí Ralph
- Kelechi Udegbe gẹ́gẹ́bí AK
- Broda Shaggi gẹ́gẹ́bí Ginja
- Bukola Beecroft-Shofola gẹ́gẹ́bí Iyaafin Kpokobri
Àfòyèmọ́
Àkòrí fíìmù náà dá lórí ọmọdékùnrin ọ̀dọ́ kan Nimbe (Chimezie Imo) tí àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ máa n dálára yá nígbàgbogbo ṣùgbọ́n láànú ri ìtùnú, ìfẹ àti ìbáramu nínú ẹgbẹ́ oníjàgídíjàgan ti òpópónà ti o ṣàfihàn nípasẹ aládúgbò alàgbà kan ti o ba pàdé. Síbẹ̀síbẹ̀, àwọn ǹkan yípadà bi o ti ṣàfihàn sí ọna ti o léwu ti gbígbé oògùn olóró káàkiri ti o di aayé ìyípadà nínú ìgbésí ayé rẹ̀. O ni ìrírí àti jẹrìí àwọn ìtaláyà ti o tẹle e, àwọn idiwọ àti àwọn àbájáde ti o ní nkan ṣe pẹ̀lú ìlòkulò oògùn. [4]
Àwọn ìtọ́kasí
Ita ìjápọ
- Nimbe , (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)
- Nimbe Archived 2025-09-05 at the Wayback Machine.
- movie reviews Archived 2025-09-05 at the Wayback Machine. on UPreviews Archived 2025-09-05 at the Wayback Machine.
- ↑ https://thenationonlineng.net/odunlade-adekola-other-actors-expose-problems-of-drug-abuse-in-nimbe/
- ↑ https://medium.com/@pelumiwrites/nimbe-a-visual-decode-of-vulnerable-teenage-boys-movie-review-b75365b50429
- ↑ https://www.premiumtimesng.com/entertainment/nollywood/355899-six-nollywood-movies-nominated-for-2019-uk-film-festival-award.html
- ↑ https://www.nollywoodreinvented.com/2019/03/coming-soon-nimbe.html
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.