Pakaja

Pa kájà tàbí Ìpa kájà tàbí Kájà ni ó jẹ́ ìkan lára ìmúra àwọn ẹ̀yà Yorùbá[1]tí àwọn ọkùnrin àti obìrin ma ń wọ̀ lé aṣọ mìíràn. [2] Kájà tún jẹ́ aṣọ tí wọ́n ma ń wọ̀ láti abíyá padà sí èjìká. Kájà ni orúkọ tí wọ́n ń pe irúfẹ́ ìmúra bẹ́ẹ̀, nígbà tí Pa kájà jẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe fún síso tí wọ́n so aṣọ náà láti abíyá. Aṣọ èyíkéyí tí ó bá wuni ni a lè lò láti fi pa kájà.[3][4]
Àwọn ìtọ́ka sí
- ↑ "Wo ìtàn Orunmila, Babaláwo àkọ́kọ́ àti ohun tó fi sílẹ̀ lọ níbí". BBC News Yorùbá. 2021-03-03. Retrieved 2023-12-31.
- ↑ Ovirih, Steve (2020-08-06). "Jegede may lose Guber victory over choice of running mate - Erelu Tinuade Mabel Onaneye.". ThePolity (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-31.
- ↑ "اداب الرافدین". radab.mosuljournals.com (in Èdè Lárúbáwá). Archived from the original on 2024-04-10. Retrieved 2024-01-04.
- ↑ Oyeniyi, Bukola Adeyemi (2015-09-08) (in en). Dress in the Making of African Identity: A Social and Cultural History of the Yoruba People. Cambria Press. ISBN 978-1-62196-719-4. https://books.google.com/books?id=NjZzCwAAQBAJ&dq=Yoruba+mens+clothing+kaja&pg=PA14-IA5.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.