Peruzzi
Peruzzi | |
|---|---|
| Background information | |
| Orúkọ àbísọ | Tobechukwu Victor Okoh |
| Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kejìlá 1989 |
| Irú orin | Afro beat, R&B |
| Years active | 2016 |
| Labels | Davido Music Worldwide |
Tobechukwu Victor Okoh (tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kejìlá, ọdún 1989), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Peruzzi, jẹ́ olórin àti akọ-orin sílẹ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọmọ ọdún méje ló wà nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kọrin.[1] Ó di gbajúgbajà òṣèré nígbà tí 2face Idibia ṣe àfihàn rẹ̀ nínú orin 'Amaka' tó kọ.[2]
Iṣẹ́ rẹ̀
Ó ni ìyàwòran ilé-ìṣeré àkókọ rẹ ní ọdún 2007 àti pé láti ìgbà náà ,ó ti ñ ṣe gbigbasilẹ orin. Peruzzi lọ sí ilé-ìwé alákọbẹrẹ Lerato ní Egbédá, Ipinle Eko, Nigeria ó sì gba Iwe-ẹri Ilọkuro Ile-iwe akọkọ rẹ. Lẹhin ipari ẹkọ ile-iwe alakọbẹrẹ rẹ, Peruzzi tẹsiwaju si Command Secondary School ni Ikeja, Ipinle Eko, Nigeria ó sì gba ìwé-èrí Ilé-iwé gíga ti Iwọ-oorun Afirika ni ọdun 2007. Peruzzi bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ pẹ̀lú Golden Boy Records ní ọdún 2016, kí Davido Music World tó gbà á wọlé sínú ẹgbẹ́ wọn ní ọdún 2018. Orin tí Peruzzi dá kọ ní ọdún 2018, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Majesty, ní ó fi ṣe àfihàn Cee-c tó jẹ́ olúborí ètò 'Big Brother Naija' ti ọdún 2018 nínú fídíò rẹ̀. Kí ó tó kọrin àdákọ rẹ̀, níṣe ni àwọn ènìyàn ń sọ pé orin-olórin ló fi ń yan, tó sì fi ń hàn.[3][4][5] Ó hàn nínú orin 2face Idibia kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Amaka".[6][7][8] Perruzzi tan mọ́ ìyàwó àfẹ́sọ́nà Davido tí orúkọ rẹ ń jẹ́ Chioma.
Àtòjọ orin rẹ̀
Orin àdákọ
- Amaka (2018)[9]
- Champion Lover (2018)
- Majesty (2018)
- Did You (2018)
- Dina (2018)
- Run am (2018)
- Craze (2018)
- Sangbana (2018)
- Run am (2018)
- Try (2018)
- For your pocket (2018)
- Bleed (2019)
- Six 30 (with Davido) (2019)
- Nana (2019)
- The Box(2020)
- Cinatti Love (2020)
- Gunshot (2020)
- Lagbaja (2020)
- Isolova (2020)
- Southy Love ft Fireboy (2020)
- Somebody Baby ft Davido (2021)
- Ready Ft Ace Berg Tm – Ready (2022) [10]
- Peruzzi Ft Reekado Banks – Ozumba Mbadiwe (Refix Cover) [11]
Àwo-orin
Àwọn àmì-eye tó ti gbà
| Ọdún | Ayẹyẹ | Àpèjúwe àmì-ẹyẹ | Recipient | Results | Ref |
|---|---|---|---|---|---|
| 2015 | The Headies | Rookie of The Year | Himself|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [14] | |
| 2018 | City People Music Awards | Rookie of the Year | Gbàá | [15] | |
| 2019 | Top Naija Music Awards | Best Collaboration with "A" List Artiste | "Pick Call Kilode" (Problinkz) | Gbàá | [16] |
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Distribution deal signed". Veterinary Record 177 (17): 450.4–450. 2015-10-29. doi:10.1136/vr.h5810. ISSN 0042-4900. PMID 26515365.
- ↑ "[Song] 2Baba - "Amaka" ft. Perruzi - Tooxclusive MP3". tooXclusive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-27. Archived from the original on 2020-08-12. Retrieved 2020-08-12.
- ↑ "Davido, Peruzzi apologise to Twitter influencer over alleged assault". Punch. Retrieved 11 June 2019.
- ↑ "Peruzzi: How I got signed to Davido's record label" (in en-US). TheCable Lifestyle. 2018-05-02. https://lifestyle.thecable.ng/peruzzi-davido-dmw-record-label/.
- ↑ "Peruzzi: 5 Things You Should Know About Davido's New Signing". news.bounce.ng. Archived from the original on 2018-07-18. Retrieved 2018-07-18.
- ↑ "Peruzzi Latest Songs and Videos 2018 – TooXclusive". TooXclusive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-07-18.
- ↑ "Singer Peruzzi under fire for reportedly slapping popular social media influencer (photo,video) legit.ng". Naij.com. 10 June 2019. https://www.legit.ng/1242541-singer-peruzzi-under-fire-for-reportedly-slapping-popular-social.html. Retrieved 10 June 2019.
- ↑ "Peruzzi Latest Song Majesty Audio And Video 2019 – Afriget". Afriget (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-06-24. Retrieved 2019-06-24.
- ↑ "2baba - Amaka Feat. Peruzzi". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-27. Archived from the original on 2021-04-20. Retrieved 2020-08-12.
- ↑ "Peruzzi Ft Ace Berg Tm - Ready". Entmediahub (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-09. Archived from the original on 2022-02-14. Retrieved 2022-02-14.
- ↑ 234hit (2022-02-14). "Peruzzi Ft Reekado Banks - Ozumba Mbadiwe (Refix Cover)". 234Hit (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-02-15. Retrieved 2022-02-15.
- ↑ "Peruzzi Drops His "Huncho Vibes" Album Today". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-08. Archived from the original on 2021-09-01. Retrieved 2021-09-01.
- ↑ BellaNaija.com (2021-04-09). "Peruzzi Serves Up Highly Anticipated Album “Rum & Boogie” | Listen". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-01.
- ↑ "Headies Awards 2015: Full List Of Winners". Channels Television. Retrieved 25 July 2021.
- ↑ "Winners Emerge @ 2018 City People Music Awards". City People Magazine. 3 November 2018. Retrieved 25 July 2021.
- ↑ "The Winners Of 2018 Top Naija Music Awards (6th Edition)". Top Naija Music Awards. Retrieved 25 July 2021.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.