Peter Sarsgaard
| Peter Sarsgaard | |
|---|---|
Sarsgaard ní òṣù kẹsán án ọdún 2019 | |
| Ọjọ́ìbí | John Peter Sarsgaard 7 Oṣù Kẹta 1971 St. Clair County, Illinois, U.S. |
| Iléẹ̀kọ́ gíga | Washington University in St. Louis |
| Iṣẹ́ | Actor |
| Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
| Olólùfẹ́ | Maggie Gyllenhaal (m. 2009) |
| Àwọn ọmọ | 2 |
| Àwọn olùbátan | Jake Gyllenhaal (brother-in-law) |
John Peter Sarsgaard ( /ˈsɑrzɡɑrd/; tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1971) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú eré Dead Man Walking ní ọdún 1995. Ó tún ṣeré nínú fíìmù independent tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Another Day in Paradise àti nínú Desert Blue. Ní ọdún kan náà, Sarsgaard kópa Raoul nínú eré The Man in the Iron Mask (1998). Sarsgaard padà di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa John Lotter nínú eré Boys Don't Cry (1999).
Fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Charles Lane nínú erẹ́ Shattered Glass, wọ́n yan Sarsgaard mọ́ ara àwọn tí ó tọ́sí àmì-ẹ̀yẹ Golden Globe Award for Best Supporting Actor. Sarsgaard ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, bí àpẹẹrẹ: K-19: The Widowmaker (2002), Garden State, Kinsey (both 2004), Jarhead (2005), Flightplan (2005), Elegy (2008), An Education (2009), Lovelace (2013), Night Moves (2013), Blue Jasmine (2013), Black Mass (2015), Jackie (2016), àti The Lost Daughter (2021). Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú àwọn eré Green Lantern (2011), Knight and Day (2010), The Magnificent Seven (2016) àti The Batman (2022).
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.