Shoki Sebotsane
| Shoki Sebotsane | |
|---|---|
| Ọjọ́ìbí | Reshoketswe Portia Mmola 10 Oṣù Kẹjọ 1977 Tzaneen, South Africa |
| Ẹ̀kọ́ | Prudens Secondary Tampere University of Technology |
| Iṣẹ́ |
|
| Ìgbà iṣẹ́ | 2000–Present |
| Olólùfẹ́ | Sello Sebotsane |
| Àwọn ọmọ | Oratilwe Kutloano Sebotsane |
Shoki Sebotsane (bíi ni ọjọ́ kẹwàá, oṣù kẹjọ ọdún 1977) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá Celia Kunutu tí ó kó nínú eré Skeem Saam.[1] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Prudebs Secondary School kí ó tó tesiwaju sì ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Tampere University of Technology. Wọn yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Golden Horn Award.[2]
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
| Àkọ́lé | Ipa tí ó kó |
|---|---|
| Death of a Queen | Grace Lerothodi |
| eKasi: Our Stories | Mapula |
| Mfolozi Street | Matshidiso Mofokeng |
| Muvhango | Tumi |
| My Perfect Family | Dawn |
| Rhythm City | Patricia |
| Skeem Saam | Ma Kunutu |
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Shoki Sebotsane". tvsa.co.za. Retrieved 2015-06-18.
- ↑ Julie Kwach (6 September 2019). "Shoki Sebotsane biography: age, weight loss, children, husband, ex husband, pictures, Skeem Saam, nominations and Instagram". briefly.co.za.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.