Smart Adeyemi
Smart Adéyẹmí (tí a bí ní Ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Kẹjọ ọdún 1960) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria láti ìpínlẹ̀ Kogí.
Ìlà kàkà rẹ̀ gẹ́gẹ́ òṣèlú
Sínétọ̀ Smart Adéyẹmí ti fìgbà kan jẹ́ ọmọ ilẹ̀ ìgbìmọ̀ aṣòfin-àgbà níbi tí ó ti ṣojú ẹkùn ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ Kogí títí di ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party. Sínétọ̀ Dino Mélayé tí ẹgbẹ́ All Progressives Congress ló borí rẹ̀ nínú ìdìbò náà. Nígbà tí ó di ọdún 2019, Smart Adéyẹmí tún díje ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, ṣùgbọ́n lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Dino Mélayé tí ó jẹ́ aṣojú ẹgbẹ́ PDP ló tún borí rẹ̀ nínú ìdìbò náà. [1] [2]
Láìpẹ́ yìí, ilé-ẹjọ́ da ìbò tó gbé Dino Mélayé wọlé nù, ó sìn pàṣẹ kí wọ́n ṣe àtúndìbò mìíràn. Ìdìbò náà ń lọ lọ́wọ́ ni ìpínlẹ̀ Kogí.[3] [4] Lẹ́yìn àtúndì ìbò náà, Smart Adéyẹmí ló wọlé gẹ́gẹ́ bí Aṣòfin-àgbà láti ṣojú apá ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ Kogí. [5][4]
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Smart Adeyemi’s Decision To Challenge My Victory Is An Action Of A “Defeated And Frustrated Man” – Melaye". Information Nigeria. 2015-04-25. Retrieved 2019-11-17.
- ↑ "Dino Melaye Vs Smart Adeyemi: INEC Fixes November 16 For Rerun Of Kogi West Senatorial Election". Sahara Reporters. 2019-10-22. Retrieved 2019-11-17.
- ↑ "2019: APC adopts Smart Adeyemi for Senate". The Sun Nigeria. 2018-07-08. Retrieved 2019-11-17.
- ↑ 4.0 4.1 "Dino Melaye leads Smart Adeyemi in race for Kogi West Senate seat". Premium Times Nigeria. 2019-02-24. Retrieved 2019-11-17. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>tag; name "Premium Times Nigeria 2019" defined multiple times with different content - ↑ Published (2015-12-15). "Congratulating Smart Adeyemi same as celebrating an armed robber —Dino Melaye". Punch Newspapers. Retrieved 2019-12-28.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.