Tango With Me
| Tango with Me | |
|---|---|
| Fáìlì:Tango with me poster.jpg Theatrical release poster | |
| Adarí | Mahmood Ali-Balogun |
| Olùgbékalẹ̀ | Mahmood Ali-Balogun |
| Òǹkọ̀wé |
|
| Àwọn òṣèré | |
| Orin | Kayode Ilelaboye |
| Ìyàwòrán sinimá | Keith Holland |
| Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Brickwall Communications LTD Jungle FilmWorks |
| Olùpín | Brickwall Communications LTD Talking Drum Entertainment |
| Déètì àgbéjáde |
|
| Àkókò | 103 min |
| Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
| Èdè | English |
| Ìnáwó | ₦100 million |
Tango with Me jẹ́ eré ónífẹ̀ẹ́ tí Femi Kayode kọ, tí wọ́n ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún un 2010 ní Nàìjíríà, Mahmood Ali-Balogun ni olùdarí, òun náà lo sì ṣe àgbéjáde eré yìí, àwọn òṣèré akópa inú eré yìí ni Genevieve Nnaji, Joseph Benjamin àti Joke Silva. Wọ́n ṣe àṣàyàn eré yìí fún àmì-ẹ̀yẹ márùn-ún níbi ìpàgọ́ àmì-ẹ̀yẹ fún àwọn eré tí wọ́n ti ṣe àgbéjáde, ẹlẹ́kèéje irú ẹ̀ 7th Africa Movie Academy Awards.[1][2][3][4][5][6][7][8][9][10]
Cast
- Genevieve Nnaji kópa gẹ́gẹ́ bíi Lola
- Joke Silva kópa gẹ́gẹ́ bíi Ìyáa Lola
- Joseph Benjamin kópa gẹ́gẹ́ bíi Uzo
- Tina Mba kópa gẹ́gẹ́ bíi Mrs. Jibike Bankole-Smith
- Bimbo Manuel kópa gẹ́gẹ́ bíi Counsellor
- Ahmed Yerima kópa gẹ́gẹ́ bíi I Bàbáa Lola
- Bimbo Akintola kópa gẹ́gẹ́ bíi Sandra
- Queen Ahune kópa gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rẹ́ẹ Lola
- Barbara Soky kópa gẹ́gẹ́ bíi Ìyáa Uzo
- Alex Usifo kópa gẹ́gẹ́ bíi bàbáa Uzo
- Kelvin Ushi kópa gẹ́gẹ́ bíi Tunde
- Matthew Onwochei kópa gẹ́gẹ́ bíi Alàgbà
- Arinze Okonkwo kópa gẹ́gẹ́ bíi Groomsman
- Fehintola Olulana as Nkiru
- Sunday Afolabi kópa gẹ́gẹ́ bíi Agbanipa 1
- Emeka Ojukwu kópa gẹ́gẹ́ bíi Agbanipa 2
- Sade Alder-Hayes kópa gẹ́gẹ́ bíi Folake
Ìtẹ́wọ́gbà
Eré yìí gbà náà gba èsì àyẹ̀wò rere àti ti bákan méjì lọ́dọ̀ àwọn lámèyítọ́. NollywoodForever fún un ní ìdá ọgọ́rin nínú ọgọ́rùn-ún, wọ́n sì kọ pé: "Tango with Me jẹ́ eré tí wọ́n yà dáadáa, pẹ̀lú orin abẹ́lẹ̀ tó bá a mu dáadáa. Joseph àti Genny dùn ún wò papọ̀, wọ́n sì ṣe ìfarahàn ìbáṣepọ̀ tó rọrùn. Mo rí i pé ó lọ díẹ̀ díẹ̀ ní àwọn apá kan, ṣùgbọ́n ìṣeré àwọn oṣèré kún fún ìtara ó sì fi ìmọ̀sílára hàn".[11]
Ẹ tún lè wo
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "AMAA Nominations 2011". Africa Movie Academy Awards. Archived from the original on 2 March 2011. Retrieved 27 February 2011. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ "Old Actors Return in Tango With Me". AllAfrica.com (AllAfrica Global Media). 18 December 2009. http://allafrica.com/stories/200912180911.html. Retrieved 27 February 2011.
- ↑ Akande, Victor (28 November 2009). "'Tango With Me'". The Nation (Lagos Nigeria). Archived from the original on 24 July 2011. https://web.archive.org/web/20110724101135/http://thenationonlineng.net/web2/articles/26871/1/Tango-With-Me/Page1.html. Retrieved 27 February 2011.
- ↑ Njoku, Banjamin (18 December 2009). "Old actors return in Tango with Me". Vanguard (Lagos, Nigeria). http://www.vanguardngr.com/2009/12/old-actors-return-in-tango-with-me/. Retrieved 27 February 2011.
- ↑ Okafor, Zik Zulu (7 January 2010). "Ali-Balogun - Nollywood's Movie Man". AllAfrica.com (AllAfrica Global Media). http://allafrica.com/stories/201001080425.html. Retrieved 27 February 2011.
- ↑ Akande, Victor (9 January 2010). "I pray my film is accepted in Cannes! —Mahmood Ali-Balogun". The Nation (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 24 July 2011. https://web.archive.org/web/20110724101158/http://thenationonlineng.net/web2/articles/31773/1/I-pray-my-film-is-accepted-in-Cannes-Mahmood-Ali-Balogun/Page1.html. Retrieved 27 February 2011.
- ↑ "Mahmood Ali-Balogun's vision becomes reality". New York, USA: Kodak. June 2010. Archived from the original on 13 July 2011. Retrieved 27 February 2011. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ Lasisi, Akeem (24 December 2010). "Ali-Balogun spurs Genevieve, Yerima to Tango". The Punch (Lagos, Nigeria). http://www.punchng.com/Articl.aspx?datex=12/24/2010&theartic=Art201012241384515. Retrieved 27 February 2011.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Kan, Toni (26 February 2011). "Heralds of the New Nollywood". This Day (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 17 July 2011. https://web.archive.org/web/20110717050839/http://www.thisdaylive.com/articles/heralds-of-the-new-nollywood/86872/. Retrieved 27 February 2011.
- ↑ Uzoatu, Uzor Maxim (April 17, 2011). "Tango with me: A movie phenomenon". Vanguard (Lagos, Nigeria). https://www.vanguardngr.com/2011/04/tango-with-me-a-movie-phenomenon/. Retrieved 17 April 2011.
- ↑ "Tango with Me | Nollywood Forever Movie Reviews". Archived from the original on 2021-11-09. Retrieved 2014-01-27. Unknown parameter
|url-status=ignored (help)
External links
- Official website
- Tango With Me , (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.