James Manager
James Manager | |
|---|---|
| Alága ẹ̀ka People's Democratic Party ti ìpị́nlẹ̀ Delta | |
| In office ọdún 1998 – ọdún 1999 | |
| Arọ́pò | Pius Sinebe |
| Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
| Ó gun orí àga ọdún 2007 | |
| Constituency | Gúúsù Delta |
| Àwọn àlàyé onítòhún | |
| Ọjọ́ìbí | Oṣù Keje 1960 (ọmọ ọdún 65) |
| Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
| Profession | Olóṣèlú |
James Manager jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Delta ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọdún 2003 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Senate Raises Panel Over Military Action". Daily Independent (Lagos). 21 May 2009. Retrieved 2009-09-15.
- ↑ "War in the Creeks of Nigeria - Stop This Carnage, Say Niger Delta Leaders". Somali Press. May 18, 2009. Archived from the original on 2012-02-16. Retrieved 2009-09-15.
- ↑ "Any Nigerian can be N-Delta minister - Senator". The Nigerian Observer. September 15, 2009. Retrieved 2009-09-15.
Content Disclaimer
Informasi ini disarikan dari Wikipedia dan disajikan kembali untuk tujuan edukasi. Konten tersedia di bawah lisensi CC BY-SA 3.0. Kami tidak bertanggung jawab atas ketidakakuratan data yang bersumber dari kontribusi publik tersebut.
- The information displayed on this website is sourced in part or in whole from Wikipedia and has been adapted for the purpose of restating it. We strive to provide accurate and relevant information, however:
- There is no guarantee of absolute accuracy. Wikipedia is an open, collaborative project that can be edited by anyone, so information is subject to change.
- It is not intended to constitute professional advice. The content displayed is for informational and educational purposes only. For important decisions (e.g., medical, legal, or financial), please consult a professional.
- Content copyright. Wikipedia is licensed under the Creative Commons Attribution-ShareAlike License (CC BY-SA). This means that content may be reused with appropriate attribution and shared under a similar license.
- Responsible use. Any risk arising from the use of information from this website is entirely the responsibility of the user.